Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Ọkunrin kan to wọ asọ shaati polo alawọ buulu n nawọ si ọkankan
  • Peter Obi wọ asọ toke tilẹ dudu ati fila rẹ, o na ọwọ rẹ mejeeji soke lati fi se apejuwe
  • Gbadebo Rhodes-Vivour wọ asọ toke tilẹ ati fila alawọ funfun, o ka ọwọ rẹ mejeeji mọ igba aya
  • Obinrin kan ń di ibo ni àgọ́ ìdìbò
  • Obinrin kan wọ kaba alawọ buluu, o we gele alawọ miliki, o n na ọwọ si ara rẹ
  • obinrin kan da iborun bo ara, wọn na amohunbugbẹmu si ni ẹnu
  • Yemi Farounbi wọ aṣọ toke tilẹ̀ funfun àmọ́ kò de fila
  • Dangote wọ aṣọ kóòtù oloyinbo dúdú, shaati funfun àti Tai pupa
  • Ike epo pupa meji ti epo pupa kun inu rẹ duro papọ
  • Agbo kan to kun inu ike gorodo funfun
  • Oluwapelumi Mutiu wọ aṣọ oplomi aro, o fẹyinti ogiri, o na apa rẹ mejeeji siwaju
  • Olori Sekinat Elegushi

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ