Oyinlọla kọ̀wé fipò rẹ̀ sílẹ̀ ni NIMC

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Oyinlọla kọ̀wé fipò rẹ̀ sílẹ̀ ni NIMC
Published

Emi kò jẹ́ dalẹ̀ ọga mi lẹ́nu iṣẹ́, ṣùgbọn tọ ipa ti ọkàn mi fẹ́ lásìkò yii ninu òṣèlu.