Irinṣẹ́ òǹkà ọdún ti wà láti ka iye ọdún tó leè lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé, iye ọdún tó ṣeé ṣe kí gbogbo ènìyàn lò láyé, ti fi ọdún méje pọ̀ si láti ọdún 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà ọdún yìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀, ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè to ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Skip Móríwú and continue reading

Móríwú

  • Patience Adekunle wọ sokoto penpe ati asọ T-Shirt, o tẹri mọlẹ n to waya to fẹ fi ya aworan
  • Gomina Abiodun Oyebamiji wọ agbada toke tilẹ alawọ eeru, o mu iwe idibo lọwọ lati dibo ni agọ idibo rẹ.
  • Obinrin alawọ funfun ati alawọ dudu
  • Ọkan lara awọn eeyan Ago Ireti niluu Akure
  • Ere idaraya abula ti won so l'oruko ounje Amala, gbegiri ati ewedu
  • Ifatolani Olori Emere
  • Adeleke
  • Ọkunrin kan to n sun lori ibusun
  • Eegun ti awọn eeyan to tẹle lẹyin
  • Shodey wọ asọ toke tilẹ dudu, o lo awo oju, o si ta irun rẹ ni koko
  • Awọn ti wọn padanu eeyan wọn ninu ikọlu ṣọọṣi Ọwọ
  • Eeyan kan ori ibusun rẹ lalẹ

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ