Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
O ma ṣe o! Ọpọ eeyan farapa, ile dawo
Latari ibugbamu meji to waye nipinlẹ Rivers ati Edo
Awon eeyan ti ko din ni marun-un la gbọ pe wọn padanu ẹmi wọn
Ki lo fa ibugbamu naa lawọn ipinlẹ mejeeji yii
Ati pe igbesẹ wo lawọn alakoso n gbe lori rẹ?
Kan soju opo BBC.COM/YORUBA
-------------------------------------------------------
Ṣe looto ni awọn ẹbi Toluwanisings n bẹbẹ fun iranwọ owo fun iyawo atawọn ọmọ rẹ?
Ẹbi Oloogbe naa sọ pe sọ pe irọ to jinna si otitọ ni
Iwe ilewọ kan ti wọn n gbe kaakiri ori ayelujara bayii sọ pe
Ki awọn eeyan da owo fun iyawo atawọn ọmọ Toluwanisings
Ta lo wa nidi iwe ilewọ naa?
---------------------------------------------------------
Ki lo fa idi ti ọmọ ọdun mẹrindinlogun kan ṣe yinbọn pa akẹkọọ mẹta nilẹ Amẹrika?
Ko ye mi o
Ọmọdekunrin naa lo yinbọn pa ọmọ ọdun marun-un, mẹjọ ati mọkanla niwaju ile-ẹkọ ni Oregon l'Amẹrika
Bẹẹ ni ibọn tun ba olukọ ẹni ọdun mẹrinlelaadọta
Ṣe loootọ ni wọn ti yinbọn pa ọmọ ọdun mẹrindinlogun ọhun?