Bí ìjọba bá tọwọ́ bọ̀wé láti ṣe ẹ̀tọ́ tí wọ́n ṣe fáwọn ASUU fún àwa náà la tó máa dẹ́kun ìyanṣẹ́lódì wa - SSANU, NASU, NAAT
Bí ìjọba bá tọwọ́ bọ̀wé láti ṣe ẹ̀tọ́ tí wọ́n ṣe fáwọn ASUU fún àwa náà la tó máa dẹ́kun ìyanṣẹ́lódì wa - SSANU, NASU, NAAT
Agbagbari jọpo ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ faṣiti apapọ ti ki ṣe olukọ iyẹn SSANU NASU, NAAT ati awọn ẹgbẹ miran labẹ asia JAC iyẹn Ẹgbẹ to so gbo oṣiṣẹ faṣiti papọ ti gun le iyanṣẹlodi nitori ijọba apapọ kọ lati fi afikun si owo oṣu wọn.
Wọn ni ijọba fi ida ogoji kun owo oṣu awọn oṣiṣẹ labẹ asia ASUU sugbọn ijoba kọ lati san owo naa fun ẹgbẹ oṣiṣẹ ti ki ṣe olukọ.
Iyanṣẹlodi yii lọ n waye jakejado gbogbo faṣiti ati ile iwe gbogbo nise to jẹ ti ìjọba apapọ to ri lẹ ede yii