Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

O pe ọdun mẹta lonii ti Bola Tinubu di Aarẹ Naijiria

Eyi to mu ileeṣẹ aarẹ yanna-na awọn aṣeyọri rẹ nipo aṣẹ.

Atẹjade ti Aarẹ fi sita ṣalaye pe ọrọ aje Naijiria ti daa ju bo ṣe wa tẹlẹ lọ.

Ati pe owo iranwọ epo ti Tinubu yọ kuro ti so eso rere fun Naijiria.

Eto aabo ti daa si I pẹlu bi Aarẹ ṣe wi.

Bẹẹ ni Aarẹ sọ pe owo ounjẹ ti walẹ pẹlu.

Ka awọn koko ọrọ Tinubu yoku ni BBC.COM/YORUBA

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Pẹpẹyẹ n pọnmọ lọwọ n'Ijebu Ode, nibi ti ayẹyẹ Ojude ọba to maa n waye lọdọọdun ti ṣẹlẹ lonii.

Gbogbo ọmọ Ijebu kaakiri agbaye lo peju pẹlu aranbara aṣọ.

BBC Yoruba wa nibi ayẹyẹ to maa n waye lọjọ kẹta ọdun Ileya naa.

Wo bo ṣe n loju opo wa.

jjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjj

"A kọlu ibudo ologun ofurufu ilẹ America nitori awọn naa ju ado oloro sọdọ wa.

Orilẹ ede Iran lo ṣalaye bẹẹ lẹyin ti wọn ni America kọlu Guusu Iran.

Ti o ba fẹ mọ si i nipa rẹ.