You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
"Ọ̀rọ̀ aláàgànná àti ọlọ́tí ni pé Oluwo wú òkú àwọn ọba tí wọ́n sín sí ààfin rẹ̀, ṣe ló tún ibòji wọn ṣe"
Awọn eeyan to sunmọ ọba Akanbi, ti wọn si mọ awọn ohun to ṣẹlẹ nipa awọn oju oori yii ti n ṣe alaye tiwọn.
Àjọ NEMA kéde agbègbè 37 tó wà nínú ewu ẹ̀kún omi, 15 l'Eko, 19 l’Ogun, 3 ní Nassarawa
NEMA ni kawọn to ba n gbe ni bebe okun lagbegbe naa tete fi ibẹ silẹ
Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 1,02
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ta ló wọlé ìbò abẹ́nú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord láti dupò Gómìnà l'Oyo láàrin Oriyomi àti Gudugudu? Ohun tí a mọ̀ rèé
Ṣaaju eto idibo naa ni ọkan lara awọn oludije ninu mẹta sipo gomina ninu ẹgbẹ oṣelu Accord, Fatai Owoseni, juwọ silẹ pe oun ko dije mọ.
Fídíò, Ìjì òjò líle sí òrúlé, da ògiri wó nílé ẹ̀kọ́ girama ọgbọ̀n l‘Ogbomoso, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ n kẹ́kọ̀ọ́ lábẹ́ ilé àlàpa, Duration 4,32
BBC News Yorùbá ṣe àbẹ̀wò sí Ogbomoso láti mọ ọṣẹ́ tí ìjì òjò náà ṣe láwọn ilé ẹ̀kọ́ girama, táwọn olùdarí àwọn iléẹ̀kọ́ náà sì ń bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́.
30,000 Fulani agbébọn àtàwọn ikọ̀ afẹ̀jẹ̀wẹ̀ míí ló ń pa ọ̀pọ̀ èèyàn, sọ ọ̀pọ̀ di aláìnílé lórí mọ́ ní Nàíjíría - Àbọ̀ ìwádìí àjọ Amẹ́ríkà
Ikede naa lo waye ninu agbejade abọ iwadii ajọ Amẹrika to wa fun ominira ẹsin ni agbaye fun osu karun ọdun 2026 to da lori ikọlu agbebọn nilẹ Naijiria.
Ta ló yẹ kó pa ẹran Ileya, ṣé ẹ̀ṣẹ̀ wà fún ẹni tí kò bá pa ẹran, kí ni ẹni tó bá fẹ́ pa ẹran gbọdọ̀ ṣe?
Ileya jẹ́ ọdún tó ṣe pàtàkì sáwọn Mùsùlùmí nítorí òhun ni wọ́n kà kún ọdún ńlá níbi tí wọ́n ti máa ń pa ẹran àgbò.
Olóòtú Ìjọba Senegal Sonko di adarí ilé aṣòfin lẹ́yìn tí Ààrẹ Faye yọ ọ́ nípò
O ti to oṣu meloo kan bayii ti faakaja ti n waye laarin Aarẹ Faye ati Olootu ijọba Sonko.
Arafat Day: Wo ohun márùn-ún tí ayájọ́ òní fi lọ́lá jùlọ nínú Islam
Ọjọ Arafa ni ọjọ kẹsan oṣu Zul-Hijjah, ni onka oṣù ojú ọrun, tii se ọjọ Arafa.
Ìrọ́ ni pé PDP dara pọ̀ mọ́ APM l‘Oyo, ẹgbẹ́ wa tóbi ju ká dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú kankan lọ, àwa lá borí ìbò ààrẹ - Gbolarumi
BBC News Yoruba ba Amofin Azeem Gbolarumi sọrọ ni kete to wọle ibo abẹle PDP bii oludije gomina fẹgbẹ PDP nipinlẹ Oyo.
Fídíò, "Ìjọba rí epo rọ̀bì ní ìlú wa àmọ́ a kò jàǹfààní kankan, kò sí omi, iná, ojú ọ̀nà, ààbò, iléẹ̀kọ́ àti ilé ìwòsàn", Duration 2,16
BBC News Yoruba ṣe àbẹ̀wò sílùú Ẹ̀bá tó pààlà láàrin ìpínlẹ̀ Ogun àti Ondo láti mọ̀ nípa àwọn àǹfààní àti ìpèníjà tó ń kojú wọn, bí ìjọba àpapọ̀ ṣe ṣàwárí epo rọ̀bí nílùú náà.
Àlàyé rèé lórí bí àwọn aṣọ́bodè ṣe gba bọ́ọ̀sì tó kún fún aṣọ ológun àti òògùn olóró tówó rẹ̀ tó ₦259.68m l'Ogun
Oju ọna marosẹ Sagamu–Ore–Benin, ni ọwọ ti ba awọn ọkunrin meji naa lọjọ Aiku ọsẹ yii, gẹgẹ bi awọn aṣọbode ẹkun Ogun Area 1 ṣe sọ.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
Fídíò, Wo atọ́kùn ètò móhùnmáwòrán tó ṣe àfihàn bí wọ́n ṣe ń yin ìbọn AK-47 lórí afẹ́fẹ́, Duration 1,21
Wọ́n ní kálukú ló gbọ́dọ̀ lè dá ààbò bo ara rẹ̀ ṣáájú ogun US àti Israel bí wọ́n bá tún padà wá
Ọwọ́ Amọtẹkun tẹ afurasí agbódegbà àwọn ajínigbé to n múra bíi wèrè l'Ondo
Ọga agba ikọ Amọtẹkun nipinlẹ naa, Akogun Adetunji Adeleye lo sọrọ yii lasiko to n foju afunrasi naa lede ni olu ileeṣẹ ajọ ọhun ni Alagbaka niluu Akure.
Ọwọ́ ọlọ́pàá Hisbah tẹ ọkùnrin tó sá pamọ́ sínú àpò "Ghana Must-Go" nílé àlè
Adari ajọ to n ri si ọrọ Sharia nipinlẹ naa, Sirajo Kamba, lo fidi iroyin naa mulẹ fun ileeṣẹ iroyin News Agency of Nigeria.
Ṣé ọmọ Naijiria láṣẹ lábẹ́ òfin láti ya fídíò ọlọ́pàá lẹ́nu iṣẹ́?
IGP Olatunji Rilwan Disu sọ pe ileeṣẹ ọlọpaa ko ni faye gba idunkoko mọ araalu lati ọwọ ọlọpaa kankan, ọlọpaa to ba si ṣe bẹẹ yoo jẹ iyan rẹ niṣu.
Ìjọba Amẹrika gbé igbésẹ̀ tuntun lórí ọ̀nà àti gba ìwé ìgbélùú 'green card'
Aṣẹ yii lo jade ninu atẹjade kan lati ọọfisi ajọ US Citizenship and Immigration Services, USCIS.
CAN gbé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ orúkọ àwọn èèyàn tí ajínigbé gbé nílé ẹ̀kọ́ mẹ́ta nípínlẹ̀ Oyo jáde, bẹ̀rẹ̀ àwẹ̀ àti àdúrà
Awọn alaṣẹ ti fi orukọ awọn eeyan to wa nigbekun awọn ajinigbe agbebọn naa lede ninu eyi ti ọmọdebinrin kan ti ọjọ ori rẹ ko ju ọmọ ọdun meji lọ wa.
Makinde ṣàgbédìde òfin tó de àwọn fijilanté àtàwọn ẹ̀ṣọ́ ààbò abẹ́nú míì
Nigba to n buwọlu ofin naa, Makinde ni ofin naa pọn dandan pẹlu bi ipenija aabo to n koju awọn ilu ati ileto ni ipinlẹ ọhun ṣe n peleke sii.
Sunday Igboho ṣe àfihàn ẹ̀ṣọ́ ààbò "Ija Ekun" tó fẹ́ fi kojú àwọn agbébọn nílẹ̀ Yorùbá bí ìjọba bá fún-un láṣẹ
Ọjọ Iṣẹgun ni Igboho sọrọ yii, pẹlu alaye pe aṣẹ ijọba apapọ ati ibuwọlu awọn gomina nikan loun n duro de lati bẹrẹ iṣẹ naa, to ba ti ya, o ya ni.
"Òfin tó mú Eleha ló mú eléégún, ẹ fààyè gbàwọn ẹlẹ́sìn àbáláyé náà láti máa wọ aṣọ ìbílẹ̀ lọ ilé ẹ̀kọ́ ISI n'Ibadan"
Amofin Bola Akioye to ṣoju awọn ẹlẹsin abalaye nile ẹjọ sọ pe ni Ọdun 2017 ti awuyewuye naa kọkọ bẹrẹ ni wọn ti le awọn ọmọ awọn ẹlẹṣin abalaye kuro ninu ile ẹkọ ISI nitori wọn wọ ilẹkẹ.
Ohun tó ṣẹlẹ̀ rèé níbi ìdìbò abẹ́nú APC sípò Gómìnà l'Oyo
Ọkan lara awọn oludije sipo gomina, Adebayo Adelabu, sọ pe ni awọn wọọdu mii awọn janduku ko je ki awọn ololufẹ oun dibo nibẹ.
Afeez Owo ṣàlàyé ohun tó fa ìyapa láàrin òun àti Mide lásìkò kan nínú ìgbéyàwó wọn
Afeez Owo sọ pe ''ija kan ṣoṣo ti mo ja ri pẹlu iyawo mi lati igba ti a ti ṣe igbeyawo naa ni igba ti a yapa.''
Saudi yóò ṣe ògbufọ̀ wáàsí ọjọ́ Arafa Hajj ọdún yìí sí Yorùbá, Hausa àti èdè mẹ́tàlélọ́gbọ̀n míì
Adari ọrọ ẹsin ni mọṣalaaṣi Anabi ni Saudi, Sheikh Abdulrahman bin Abdulaziz Al-Sudais, ni o fidi ọrọ yii mulẹ.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Mo ṣetán láti dupò ààrẹ ní 2027, ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ ni ìdìbò abẹ́lé wa- Omoyele Sowore
Tẹ o ba gbagbe, Sowore du ipo aarẹ Naijiria ni 2019 ati 2023, ṣugbọn ipo naa ko bọ si I lọwọ.
Ta ni Joel Adesiyan, olùkọ́ táwọn agbébọn pa l'Ogbomoso, àti pé, ṣé òun ni wọ́n pa ní àhámọ́ àwọn ajínigbé?
Idile onígbàgbọ ní a bi Joel si nibi t'awọn obi rẹ si kọ ọ ni ẹkọ ọrọ Ọlọrun bi o ti n dagba.
Ẹ wo àwọn olùdíje tó wọlé àtàwọn tó lulẹ̀ nínú ìbò abẹ́nú APC sípò Gómìnà láwọn ìpínlẹ̀
Ọpọ awọn gomina to ti ṣe saa kan tẹlẹ lo gba tikẹẹti lati ṣe saa keji, nigba tawọn to ti ṣe saa keji ri pe awọn eeyan ti wọn fẹ lọ wole idibo abẹnu awọn oludije fun ipo gomina.
Ṣé lóòótọ́ ni pé àwọn ajínigbé tó ṣọṣẹ́ l'Ogbomoso ti ń bá ìjọba Oyo sọ̀rọ̀? Ohun tí a mọ̀ rèé
Ireti ọpọ ọmọ Naijiria ni pe awon ajinigbe naa yoo tete ba ijọba sọrọ, ki awon to wa nigbekun le gba ominira.
Ṣé òótọ́ ni pé Ààrẹ Tinubu fẹ́ pa orúkọ Naijiria dà tó tún fẹ́ wọ́gilé òfin Sharia ní Naijiria?
Ninu atẹjade kan ti agbẹnusọ Aarẹ, Bayo Onanuga, fi lede, o ni irọ nla gbaa ni iroyin naa ati pe awọn to n gbe iroyin ọhun kiri fẹ mọọmọ fi da wahala silẹ ni Naijiria ni.
Obasanjo ṣàlàyé irúfẹ́ àìsàn tó ti ń bá a fínra fún bí ogójì ọdún àti ọ̀nà tó fi ń tọ́jú ara rẹ̀
Aarẹ ana orilẹede Naijiria to ti pe ẹni ọdun mọkandinlaadọrun un bayii fidi ọrọ naa mulẹ ninu ifọrọwanilẹwo kan to ṣe niluu Abeokuta lopin ọsẹ to kọja.
"Agbekoya ní agbára ìbílẹ̀ láti lé àwọn jàndùkú afẹ̀míṣòfò kúrò ní gbogbo ilẹ̀ Yoruba láàrin oṣù kan péré, àmọ́..."
Ọgbẹni Bankole Ahmed sọ pe Agbekoya ti ja oniruuru ija bayii sẹyin ti wọn si ṣẹgun.
Gómìnà Seyi Makinde ní ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo ṣetán láti jíròrò pẹ̀lú àwọn agbébọn tó jí akẹ́kọ̀ọ́, olùkọ́ gbé kí wọ́n lè tètè padà wálé
Gomina Makinde rawọ ẹbẹ sawọn agbebọn to ji awọn eeyan naa gbe pe ki wọn jeburẹ, ati pe ijọba ṣetan lati joko sọrọ lati mọ ohun ti wọn ba fẹ lati tu awọn to wa lahamọ wọn silẹ.
Ọlọ́pàá ṣàlàyé bí àwọn alamí ṣe ran àwọn ajínigbé tó kọlu iléẹ̀kọ́, jí akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ gbé l'Oyo lọ́wọ́
Mẹfa ninu awọn alami naa lọwọ ọlọpaa ti tẹ bayii.
Àwọn ọmọdékùnrin méjì ṣekúpa èèyàn mẹ́ta nínú mọ́ṣáláṣí, pa ara wọn lẹ́yìn rẹ̀
Ọlọpaa ti n wa awọn ọmọ naa ko to di pe ikọlu waye si mọṣalaṣi San Diego, ti wọn si ba awọn tawọn ọmọ naa yinbọn fun niwaju mọṣalaṣi naa pelu oju ọgbe ọta ibọn lara.
Èèmọ̀ dé! Èyí làwọn bàbá tó ń ta ọmọ gbowó nítorí àti jẹun
Ni Afghanistan lonii, eeyan mẹta ninu eeyan mẹrin ni ko ni ohun ti wọn n fẹ lati fi gbe aye gẹgẹ bi ajọ iṣọkan agbaye ṣe sọ.
"Ọlọrun ti gba ọkọ mi!" Niniola, gbajúmọ olórin tàkasúfèé kéde ikú ọkọ rẹ̀
Ko tii si ẹni le sọ ohun gan to ṣe okunfa iku ọkọ gbajumọ akọrin naa.